Eto Ilera

 1. Video content

  Video caption: Olusegun Obasanjo: Ọmú ìyá mi ti mo fi ń mùkọ ni kekere ló jẹ ki ń lókun

  Gbogbo ohun ribiribi ti mo ti gbé ilé aye ṣe Ọlọ́run yọ̀nda rẹ̀ fun mi ni kìí ṣe mímọ̀ọ́ṣẹ àti agbára mi ló jẹ ki gbé ilé àyé ṣe rere

 2. Faiza Autistic Girl: Ọ̀pọ̀ ìgbà ni mó má n so lọ́wọ́, ẹsẹ̀ àti ẹnu kó ma baa pariwo- Ìyá Faizat

  "Iṣẹ́ àgbàṣe ni ká ba àwọn ènìyàn fọ ilé fọ ilẹ̀ tàbi nígbà mírà kí n tẹ̀lé àwọn ẹlẹ́ràn láti lọ maa yọ ìfun ẹràn no mo fí n tọjú òun àti àwọn àbúrò rẹ̀."

  Kà Síwájú Síi
  next