Ayederu Iroyin

 1. Seyi Makinde ati Alao Akala

  Atẹjade kan ti ẹgbẹ APC ati Adebayo Alao Akala fisita lori isẹlẹ naa lọjọ Ẹti, ni iwa aimọ ojuse ẹni to tii buru julọ ni Seyi Makinde hu.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Covid-19: Wo ìròyìn òfegè mẹ́jọ táwọn adarí ẹ̀sìn ń sọ nípa àbẹ́rẹ́ àjẹsára Coronavirus

  Oluwadi nipa abẹrẹ ajẹsara to n tako arun Coronavirus ni fasiti Washinton, Kolina Koltai salaye fun BBC nipa ìroyin ofege to lu igboro pa.

 3. Video content

  Video caption: Fulani-Yoruba Crisis: Oba Soun ló fí mi jẹ ọba Sabo ni Ogbomọṣọ- Alh Haruna Bala Abdulsala

  Oba Haruna Bala sọ fun BBC pe: Oba Ṣọun ni kí n maa ṣakoso gbogbo ẹya to ba n gbe ni Sabo gẹgẹ bii ọba wọn ni Ogbomọṣọ..

 4. Bata awọn akẹ́kọ̀ọ́ ti wọn ji gbe

  Lakotan, onkọwe yii ni bi awọn ileeṣẹ iroyin ilẹ okeere yìí ti n ṣe agbekalẹ iroyin lori awọn janduku ajinigbe ati Boko Haram ṣe pataki.

  Kà Síwájú Síi
  next