ọkọ ofurufu to n wa ara rẹ

  1. Video content

    Video caption: African Eye: Ìwádìí BBC lórí ikú tó pa ọmọ ogun 26 ní Libya láti ipasẹ̀ Díróònù àìmọ̀dí

    BBC Africa Eye ṣe àwárí rẹ̀ pé, ilẹ̀ United Arabi Emirate UAE ati Egypt lo n fi diroonu sere ọwọ lorilẹede Libya, eyi ti ko jẹ ki ogun sinmi nibẹ.