Donald Trump

 1. Video content

  Video caption: Joe Biden Innauguration: Tani ìyàwó Joe Biden tí yóò jẹ obìnrin akọ̀kọ nílẹ̀ Amẹrika?

  Ogunjọ, oṣu yii ni wọn yoo burawọle fun Joe Biden gẹgẹ bi aarẹ aadọta ilẹ Amẹrika.

 2. Aarẹ Donald Trump

  Àwọn aṣòfin mẹ́wàá látinú ẹgbẹ́ òṣèlu Republican tó jẹ́ ti Donald Trup ló darapọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ alátakò Democrat lórí àti yọ ààrẹ náà nípò.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Aworan Biden ati Trump

  Ẹnikẹni to ba fẹ di aarẹ lorilẹ-ede Amẹrika gbọdọ ni ibo to pọ julọ laarin awọn ọmọ igbimọ agbaọjẹ oludibo alaṣẹ (Electoral System)

  Kà Síwájú Síi
  next