Ere ori Itage

 1. Aworan Baba Suwe ati Elesho

  Akojọpọ iroyin ree nipa bi adura ọjọ kẹjọ se waye fun Baba Suwe ati ọrọ tawọn agba osere tiata sọ nipa rẹ lẹyin iku agba osere naa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Yinka Ayefele on Davido: Ìbọ̀wọ̀ fágbà tí olórin Davido ní kọjá N250M tó fún àwọn ọmọ aláì

  Agba olorin Yinka Ayefele sọrọ nipa bi owo gọbọi ti Davido y ko fi ṣe ọjọ ibi amọ to fun awọn ọmọ alailobi ṣe fi kun iwa rere to ti ni tẹlẹ.

 3. Adesola ati Baba Suwe

  Adesola Omidina fi ọwọ sọya pe oun nigbagbọ pe orukọ baba oun ko ni parun pẹlu Ọlọrun ati atilẹyin awọn osere tiata, alagbata fiimu atawọn oludari ere.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Baba Suwe pẹlu ajọ NDLEA

  Aye gbọ, ọrun mọ nigba ti Baba Suwe wọ kaa ilẹ sun l'Ọjọbọ tori aisan ọlọjọ pipẹ lẹyin to bọ ninu ọran ẹsun gbigbe oogun oloro.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Video content

  Video caption: Gbọ́ ohun ti àwọn òṣèré tíátà Yoruba sọ fún BBVC nípa Baba Suwe

  Yatọ si awọn eeyan wọnyii, Dejo Tunfulu, Kamilu Konpo atawọn oṣere mii naa tun sọrọ nipa irufẹ ẹni ti Baba Suwe jẹ si awọn.

 6. Video content

  Video caption: Baba Suwe: Aya àkọ́fẹ́ olóògbé ṣàlàyé bí àkókó ìkẹyìn ọkọ́ rẹ̀ ṣe rí

  Ayodele Suwebatu tii se aya akọfẹ Baba Suwe ba BBC Yoruba sọrọ lori ohun to sẹlẹ nigba ti ọkọ rẹ fẹ jade laye.