Ipinlẹ Kwara

 1. Video content

  Video caption: Alhaja Rukayat Batimoluwasi Oniwaka: Orin Wákà la fi ń ṣe Wáàsí, o tó ọdún 70 tí mo tí bẹ̀

  Alhaja Rukayat Batimoluwasi, agba ọjẹ oniwaka ni Ilorin gbalejo BBC Yoruba, o ṣalaye ohun ti oju rẹ ti ri lẹ́nu iṣẹ yii.

 2. NSCDC

  Ajọ ẹṣọ alaabo abo ara ẹni, laabo ilu, Civil Defence nipinlẹ Kwara, ti mu ọkunrin ẹni ọdun 60 kan to fi ipa ba ọmọ ọdún 9 lo pọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Alakuko/Elega Schools: Aráàlú ní olùkọ̀ọ́ àti akẹ́kọ̀ọ́ ti sá ní kíláàsì tí kò dára

  Nigba ti BBC Yoruba se abẹwo si awọn ile ẹkọ to wa ni abule Iyana Alakuko ati Elega, awọn olukọ ati araalu ni ọpọ olukọ ati akẹkọọ ni ko wa sile iwe mọ nitori ewu to wa nibẹ.

 4. UNILORIN

  Nigba ti BBC kan si agbẹnusọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Kwara, Ajayi Olasunkanmi lori iṣẹlẹ ọhun, o ni lootọ ni akẹkọọ naa ti jade laye.

  Kà Síwájú Síi
  next