Oogun to n pa kokoro inu ara

 1. Ile epo

  Minisita keji fọrọ epo rọbi wa n rọ awọn alagbata epo lati mase sọ owo ọja wọn di ọwọn tabi ti ileepo wọn pa, ki ọwọn gogo epo le wa fun araalu.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Ooni nibi ifilọlẹ oogun ibilẹ covud 19

  Ooni sọ pe ajọ WHO gan an fidi rẹ mulẹ pe orilẹede Naijiria ni awọn egbo to wulo fun ṣiṣe abẹrẹ fun wiwo ọpọlọlọpọ arun.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Gomina Babajide Sanwo-Olu atawọn eleto ilera to n tọju covid-19

  Ẹru n ba ọpọ eeyan nipinlẹ Eko pe o ṣeeṣe ki iyanṣẹlodi awọn dokita ko pẹ eyi ti yoo ṣakoba fun itọju awọn alaarun covid-19.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Idanwo abẹrẹ covid-19 nilẹ Gẹeṣi

  Ẹ gbẹ onimọ ijinlẹ oogun oyinbo kan wa ni fasiti Oxford nibi ti wọn ti n ṣagbeyẹwo abẹrẹ kan ti wọn n pe ni ''ChAdOx1 nCoV-19.''

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Video content

  Video caption: Njẹ Chloroquine nipa kankan lati le koju Coronavirus

  Ẹkunrẹrẹ alaye ni a mu tọ yin wa lori awọn ohun to jẹ ootọ nipa aisan Coronavirus

 6. Video content

  Video caption: Pneumonia: Dókítà ní kòkòrò àìfojúrí ló ń fàá

  Dokita Afeez Oladele tun fikun pe a le sun si ilẹ lasan tabi gba ẹrọ amuletutu sara lai wọ ẹ́wu, ti a ko si ni ko aisan otutu aya.

 7. Oniṣegun ibilẹ

  Dókítà Adedayo Faduyile ni kíkọ́ iṣẹ́ ìṣègùn ìbílẹ̀ ní iléèwé gíga yóò dẹ́kun àwọn ayédèrú oníṣègùn ìbílẹ̀ tó wà káàkiri Nàìjíríà báyìí.

  Kà Síwájú Síi
  next