Orilẹede India

 1. India Cremation: Òkú jíndé nígbà tó ku ìṣẹ́jú péréte ti wọ́n yóò se ètò ìkẹyìn fun

  Súgbọ́n bí ó ṣe ku ìṣẹ́jú pérété tí tí wọ́n yóò ṣáná sí àwọn igi tí wọ́n ti kò fún sísun rẹ̀ ló bá lajú, ìyàlẹ́nu sì ló jẹ́ fún pe ó bá àra rẹ̀ níbí tí wọ́n ti fẹ́ dána sun.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: India, Coronavirus: Ìtọ́jú aláìsàn ló jẹ́ mi lógún nítorí ètò ìlera wa mẹ́hẹ- Nọ́ọ̀sì Kama

  Lọwọlọwọ ni orilẹ-ede India atawọn to yii ka n koju iṣoro Covid 19 to n gab ẹbọ lọwọ wọn.

 3. Video content

  Video caption: India Corona scourge: Àlàyé rèé lórí ohun tó ń fa bí kòkòrò COVID-19 India ṣe búrẹ̀kẹ̀

  Fidio yii lati ilẹ́esẹ́ BBC lo n salaye idi ti ọwọ́jà arun Coronavirus se gbinaya lorilede India lnu lọ́ọ́lọ́ yii.

 4. Awọn afurasi ajinigbe

  Majeobaje ni ti awọn gomina ilẹ Kaarọ Oojire ko ba daabo bo araalu, awọn araalu le se ohun to wu wọn lati daabo bo ẹmi ati dukia wọn.

  Kà Síwájú Síi
  next