Ipinlẹ Anambra

 1. Nnamdi Kanu

  O ti ṣe diẹ ti Nnamdi Kanu ti wa lahamọ lọdọ awọn ikọ ọtẹlẹmuyẹ DSS Naijiria gẹgẹ bi awọn agbẹjọro rẹ ti ṣe sọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Awọn ọlọpaa n gbaradi

  Igbesẹ naa ṣe pataki lẹyin ti wọn ṣe ọfintoto awọn wahala to lee fẹ bomipana alaafia lasiko idibo sipo gomina to n bọ lọna nipinlẹ Anambra.

  Kà Síwájú Síi
  next