Orilẹede Naijiria

 1. Video content

  Video caption: Romeo and Juliet padà di ìwé Akinola àti Arike ní èdè Yorùbá

  Fun ọpọ eeyan ti awọn gẹẹsi atijọ to wa ninu iwe Romeo and Juliet ko ye, anfaani ree lati gbadun itan ifẹ awọn ololufẹ meji naa ni ede Yoruba, eyi to di Akinola ati Arike.

 2. Video content

  Video caption: Awo Stage Play: Wo eré, ijó àti orin tó ń kọ́ wa lẹ́kọ̀ọ́ nípa ayé Awolowo àti aya rẹ̀

  BBC Yoruba wa pẹlu igbakeji aarẹ, Yemi Osinbajo, aya rẹ, Babajide Sanwo-Olu àti Segun Awolowo ti wọn wa lara eeyan pataki to wo ere onise nipa Awolowo ati aya rẹ.

 3. Kazeem Abonde

  Ninu atẹjade ti alukoro ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko, Adekunle Ajisebutu fi ṣọwọ si awọn akọroyin, o ni ẹmi ọga ọlọpaa ọhun sọnu lasiko ti wọn lọ fofin de awọn ọlọkada lagbegbe ọhun.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. NYSC ti sọja na

  Ọpọlọpọ igba ni awọn ẹgbẹ ajafẹtọ ọmọniyan ti ma n fi ẹsun kan ileeṣẹ oloogun Naijiria pe wọn ma n fi iya jẹ araalu lọna aitọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Monsurat Ojuade

  Laipẹ yii ni ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko sọ pe awọn ti fi ṣikun ofin mu ọkan lara awọn oṣiṣẹ rẹ to yinbọn pa ọmọ ọdun mejilogun kan nipinlẹ Eko.

  Kà Síwájú Síi
  next
 6. Noosi

  Ni ipinlẹ Delta ni Abubakar ti sọ ọrọ yii lasiko to n gba awọn Nọọsi ti wọn ṣẹṣẹ ṣe idanwo abajade tan ni iyanju nipinlẹ naa.

  Kà Síwájú Síi
  next