Oba oke pada fi ọmọkunrin lanti lanti jinki Banky W ati Adesua eyi ti wọn pe orukọ rẹ ni Zaiah.
Kà Síwájú SíiIlera awọn obinrin
Video content
Video caption: Blighted Ovum: Obìnrin kan sọ ohun tójú rẹ̀ rí nígbà tí oyún bàjẹ́ lára rẹ̀ ní ẹ̀ẹ̀mẹta Dokita onimọ nipa ọmọ bibi wa salaye ohun to n fa oyun bibajẹ ati ọna abayọ si.
Video content
Video caption: Ogbomoso Quitdruplets: Ọ̀kan nínú àwọn ìbarùn-ún jáde láyé lọ́jọ́ karùn-ún Funmilayo Oluwadara ni ọmọ mẹta ni dokita sọ pe oun yoo bi amọ marun lo bi lai fi isẹ abẹ gbẹbi rẹ.