Tí a fiṣọwọ́ ní 5:185:18Wo oríṣìí àrùn márùn ún tí ìgbéyàwó láàrin ìbátan si ìbátan máa ń fàDokita Ibrahim Musa to jẹ akọṣẹ-mọṣẹ nipa arun inu ẹjẹ sọ pe, igbeyawo laarin ibatan ni ewu ninu nitori awọ̀n arun ajẹ́bi ti wọn le jogun.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 5:025:02Ǹjẹ́ ó ṣeéṣe kí ìyáwò rẹ gbé ọmọ àlè wá sílé láì mọ̀?BBC Yoruba, ninu iwadii alagbara yii se awari ọna meje ti asise fi le waye, ti ọmọ ale yoo si foju han lai jẹ pe obinrin kan yan ale.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 9:49 11 Sẹ́rẹ́ 20219:49 11 Sẹ́rẹ́ 2021Mo ti gba ọmọ Igbo tó ń wá bàbá rẹ̀ bí ọmọ, kó má ba à pa ara rẹ̀ - Iba OluyoleVivian gan ti faake kọri pe oun ko wa baba kankan kiri mọ nitori oun ti mọ Alhaji Nureni Akanbi ni baba, oun si ti lọ gbadura si.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 11:32 4 Sẹ́rẹ́ 202111:32 4 Sẹ́rẹ́ 2021Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé rèé lórí àyẹ̀wò DNAAwọn Dokita onimo nipa eto iwosan ati eje salaye ohun ti ayẹwo DNA jẹ ati ọna ti a le gba ṣe e.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 11:24 4 Sẹ́rẹ́ 202111:24 4 Sẹ́rẹ́ 2021Nǹkan márùn ún tó yẹ kí o mọ̀ nípa Ọ̀gá Àgbà fásitì UNILAG tẹ́lẹ̀rí, Ibidapo Obe tó jáde láyéỌjọ Isinmi, Ọjọ Kẹta, Oṣu Kini, ọdun 2021 ni ẹmi bọ lara Ibidapo Obe to jẹ Ọ̀gá Àgbà fásitì UNILAG tẹ́lẹ̀ríKà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 11:51 30 Ọ̀pẹ̀ 202011:51 30 Ọ̀pẹ̀ 2020Ta ni Ọ̀jọ̀gbọ́n àkọ́kọ́ nípa ìmọ̀ ọ̀daràn ní Nàíjíríà, Femi Odekunle tí Covid-19 pa?Ọjọgbọn Odekunle lo dagbere faye ni ibudo iyasọtọ fun awọn alarun Coronavirus to wa ni Gwagwalada ni ilu Abuja nirọlẹ ọjọ Isẹgun.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 5:42 30 Ọ̀pẹ̀ 20205:42 30 Ọ̀pẹ̀ 2020Bí Nàíjíríà bá fẹ́ kí ọdún 2021 dára, ohun tí yóò ṣe rèé - ObasanjoObasanjo wa tẹnumọ pe o yẹ ka sisẹ lorilẹede yii, gẹgẹ ba se n gbadura ninu ọdun tuntun 2021, ko le jẹ ọdun ologo fun wa, amọ lai jẹ pe a sisẹ, eyi ko le ri bẹẹ.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 6:30 29 Ọ̀pẹ̀ 20206:30 29 Ọ̀pẹ̀ 2020Ẹ wo àwọn ìlúmọ̀ọ́ká ọmọ Nàíjíríà tó jáde láyé lọ́dún 2020Aarun Coronavirus wa lara aisan to mu ọpọlọpọ awọn eeyan to gbajumọ lorilẹede Naijiria lọ lọdun 2020.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 13:58 25 Ọ̀pẹ̀ 202013:58 25 Ọ̀pẹ̀ 2020Kí ló mú àwọn ẹni ọdún 90 méjì yìí ṣẹ̀ṣẹ̀ máa gbéyàwó lásìkò yìí?Trevor ati Lily wa lara awọn arugbo ti yoo kọkọ gba abẹrẹ̀ ajẹsara COVID-19 ni Bradford.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 12:23 25 Ọ̀pẹ̀ 202012:23 25 Ọ̀pẹ̀ 2020Ṣé lóòtọ́ ni Bimpe Oyebade lóyún fún Lateef Adedimeji?Adebimpe Oyebade ba BBC Yoruba sọrọ lori ibaṣepọ rẹ pẹlu akẹ́ẹgbẹ rẹ, Lateef Oladimeji.Kà Síwájú Síinext