Ajọ elere Bọọlu lagbaye

 1. Oju patako goolu

  Orilẹede Mongolia wa ni ipo aadọwa (190) ninu atẹ igbelewọn awọn orilẹede to n gba bọọlu lagbaye labẹ ajọ FIFA.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Samson Siasia

  Loṣu kẹwaa, ọdun 2019 ni ajọ FIFA fẹsun kan Siasia pe o gba lati gba riba lati ṣe eeru ninu awọn ifẹsẹwọnsẹ kan.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Minisita Dare ati awọn Golden Eaglets

  Nnkan ko kọkọ ṣẹnu 're fawọn ọjẹwẹwẹ Naijiria lẹyin ti Gyorgy Komaromi gba bọọlu sawọn fun ikọ agbabọọlu Hungary lẹyin iṣẹju mẹta ti ere bọọlu naa bẹrẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next