Ara tuntun

 1. Video content

  Video caption: Female Car AC Repairer: Abimbola Adedigba ní àfojúsùn òun ni láti ní abúlé mẹkáníkì láìpẹ́

  Abimbola Adedigba ni iya oun lo se koriya fun oun lati kọ isẹ titun ẹrọ ọlọyẹ inu mọto se, ti oun ko si kabamọ rẹ.

 2. Video content

  Video caption: Soiless Farming: Samson Ogbole ní táwọn irè oko bá fara kan ilẹ̀, ló ń kó àrùn bá wọn

  Samson Ogbole, agbẹ to n lo fulufulu eepo irẹsi lati sisẹ ọgbin lai lo erupẹ ba BBC Yoruba sọrọ lori ọna ti a le gba gbin eso ati ewebẹ yika ọdun.

 3. Video content

  Video caption: Snail Slim Soap: Wo ọ̀pọ̀ àǹfààní tó wà nínú lílo ọ̀ṣẹ tí wọn fi omi ìgbín ṣe láti fọ ojú?

  Iwadii kan ree to sọ nipa ọpọ anfaani to wa nidi lilo omi ara igbin to n yọ, fi se ọsẹ lati fi fọ oju rẹ.

 4. Video content

  Video caption: Face Transplant: DiMeo ṣùn lásìkò tó n wa ọkọ̀ lálẹ́, ló bá jóná nígbà tí ọkọ̀ gbiná

  Awọn ẹbi Joseph DiMeo lo seto bawọn dokita naa se sisẹ abẹ fun nigba mẹta lẹyin osu mẹjọ to ni ijamba naa,

 5. Video content

  Video caption: Female Car Painter: Èmi ní obìnrin àkọ́kọ́ tí yóò máa ṣiṣẹ́ akunmọ́tò ní Ibadan

  Modupe Olagunju ba BBC Yoruba sọrọ lori bo se bẹrẹ isẹ kikun mọto ni ọda ati ọpọ idojukọ to n ba pade lẹnu isẹ naa.

 6. Video content

  Video caption: Pure Water Lylon Art: Adejoke ní ohun èlò ta fi ọ̀rá ṣe ń ní àlòpẹ́, kìí tètè jẹ

  Adejoke Lasisi ni amulo ọra atawọn asọ aloku fun ipese ohun mere-mere n pese isẹ oojọ, to si n mu ki ọrọ aje ru gọgọ si.

 7. Video content

  Video caption: Nigerian Drone Maker: Roqeeb Aderogba ní ìgbà mẹ́fà l‘òun kùnà láti ṣe dírónù, kó tó yege

  Akẹkọọ fasiti naa wa rọ ijọba lati maa pese owo iranwọ fawọn akẹkọọ ni fasiti to ba n se ohun ara bi iru eyi nitori owo eroja Dírónù wọn pupọ.

 8. Video content

  Video caption: Adebunmi Adeyeye: Mo jẹ gbèsè gbọ́múléláńtà, ìdí iṣẹ́ kabúkabú ni mo ti ri san

  Adebunmi Adeyeye, tii se iya ọlọmọ kan ti ko ni ọkọ, tun sọ ọpọ iriri to ti ni nidi isẹ Kabukabu fun BBC Yoruba.

 9. Video content

  Video caption: Amope Onibata: Kìí ṣe gbogbo ọkùnrin ló gbà kí ń ṣe bàtà fún àwọn

  Olamide Adeyemi, ti ọpọ eeyan mọ si Amope Onibata ba BBC Yoruba sọrọ lori ohun to gbe de idi iṣẹ bata sise gẹg bi akẹkọjade ni fasiti.