Ehonu

 1. Lai

  Saraki sọ pe o ṣe ni laanu pe ko ti i si ayipada kankan lori awọn iwa ti ko tọ ọ ti awọn oṣiṣẹ eleto aabo ń hu.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: EndSARS rememberance: Ohun táwọn afẹhóúhàn bèrè fún ní Lekki lónìí rèé

  Oju akọroyin BBC gaaani ọpọlọpọ nkan, lara awọn to jẹ gbankọgbi nibi ayajọ EndSARS tọdun yii rèé.

 3. ENDSARS

  Lara akọle ti wọn mu lọwọ n fi ariwo bọ ẹnu pe, "ẹ tu Sunday Igboho silẹ, ki i ṣe ọdaran, ki i ṣe adẹrubalu".

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Endsars

  Okpe to jẹ awakọ ni ohun to jẹ ki oun darapọ mọ iwọde Endsars lọdun to kọja ni pe ifiyajẹni awọn ọlọpaa buru jai.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Endsars

  Ogunjọ, Osu Kẹwaa, ọdun 2021 ni awọn ọdọ ṣe ifẹhọnuhan ni agbegbe Lekki tako ifiyajẹni ati iṣekupani awọn ọmọ Naijiria gba ọwọ awọn ọlọpaa ni Naijiria.

  Kà Síwájú Síi
  next
 6. Benue

  Àwọn òṣìṣẹ́fẹ̀yìntì bẹ̀rẹ̀ ìwọ́de ni Benue lẹ́yìn tí ìjọba kò san owó oṣù wọn fún ọdún mẹ́ta.

  Kà Síwájú Síi
  next
 7. OAU

  Awọn alaṣẹ fasiti Obafemi Awolowo, OAU ti paṣẹ fun awọn akẹkọọ lati maa lọ si ile wọn ti wọn si ti ọgba fasiti naa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 8. OAU

  Igbimọ alasẹ fasiti Obafemi Awolowo ti wa rawọ ẹbẹ sawọn akẹkọ lati mase fa wahala lati pagi dina idanwo ilaji simẹsita to n lọ lọwọ/

  Kà Síwájú Síi
  next