Tí a fiṣọwọ́ ní 17:29 30 Ẹrẹ̀nà 202117:29 30 Ẹrẹ̀nà 2021Ṣe bọ́ọ̀lù àfesẹ̀gbá lèyí àbí àfọwọ́gbá? Wo orílẹ̀èdè tó jẹ góòlù 14-0 ní ìdíje bọ́ọ̀lù kan ṣoṣoOrilẹede Mongolia wa ni ipo aadọwa (190) ninu atẹ igbelewọn awọn orilẹede to n gba bọọlu lagbaye labẹ ajọ FIFA.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 8:35 30 Ẹrẹ̀nà 20218:35 30 Ẹrẹ̀nà 2021Gbọ́ àsọtẹ́lẹ̀ ìdíje àti bí o ṣe lè wo ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ láàrin Nàìjíríà àti ikọ̀ LesothoÌrètí ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù Super Eagles ni láti parí ifẹsẹwọnsẹ wọ́n fún pégedé Idije Afcon èyí sì ni láti borí Ikọ̀ Crocoldile Lesotho.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 13:41 29 Ẹrẹ̀nà 202113:41 29 Ẹrẹ̀nà 2021Gbajúgbajà akọ́nimọ̀ọ́gbá eré bọ́ọ̀lù Laloko tó ṣàwárí Mikel Obi àti Osaze dágbére fáyéAwọn ẹbi ti kede pe wọn yoo sin Laloko to jẹ Olori Parakoyi ilu Egba si ile rẹ to wa lagbegbe Gbonagun niluu Abeokuta.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 18:42 27 Ẹrẹ̀nà 202118:42 27 Ẹrẹ̀nà 2021Naijiria sán bàntẹ́ ìyà fún Benin, ó tún kójú òsùnwọ̀n fún Nations CupẸgbẹ agbabọọlu Super Eagles bori ninu ifẹsẹwọnsẹ pẹlu Squirrel ti Benin RepublicKà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 14:08 25 Èrèlè 202114:08 25 Èrèlè 2021Àbẹ̀wò wa si ọjà Ṣàsá rèé lẹ́yìn gbogbo rògbòdìyàn tó wáyé nílùú IbadanAwọn ontaja naa parọwa si ijọba lati mu ileri ṣẹ fun imubọsipo ọja naa.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 13:49 10 Èrèlè 202113:49 10 Èrèlè 2021Bàyìí ni Yisa Sofoluwe, agbábọ́ọ̀lù Super Eagles tẹ́lẹ̀ ṣe jà jà lórí àìsàn kó tó dágbéré fáyéSofoluwe ni agbabọọlu ẹyin to n dile mu nigba aye rẹ, ti gbogbo aye si mọ ọ si "Dean of Defence".Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 11:08 28 Ọ̀pẹ̀ 202011:08 28 Ọ̀pẹ̀ 2020Ẹ wo àwọn èèkàn eléré ìdárayá tó bá ọdún 2020 lọBi a ba wo agbo osere ere idaraya, awọn tó ba ọdún yi lọ yala lati ipasẹ Covid-19 tabi nnkan mii, pọ yanturu.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 9:19 23 Ọ̀pẹ̀ 20209:19 23 Ọ̀pẹ̀ 2020Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ ayédèrú Ahmed Musa tó ń lu àwọn èèyàn ní jìbìtìIleeṣẹ ọlọpàá ipinlẹ Kano fi ṣikun ofin mu ọkùnrin kan tó ń pe ara rẹ̀ ni Ahmed Musa.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 8:01 28 Bélú 20208:01 28 Bélú 2020Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ ASUU tí gbà láti fòpin sí ìyanṣẹ́lódí lẹ́yìn tí ìjọba gbà látí sàn N70bn ṣùgbọ́n...Ajọ ASUU sọ pe o yẹ ki iroyin ayọ le jade ni Ọjọọru ọsẹ yii nigba ti wọn ba tun ṣepade ipẹlu ijọba.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 18:22 25 Bélú 202018:22 25 Bélú 2020Àwòrán rèé nípa bí 'Hand of God' ṣé dí inagijẹ Diego MaradonaOrisi aworan lo safihan igbe aye gbajugbaja agbabọọlu to ṣe akọnimọọgba Messi.Kà Síwájú Síinext