Oogun

 1. Oogun amu-nkan ọkunrin le

  Ajọ NAFDAC ni ọpọlọpọ ni ko mọ awọn ipalara ti aṣilo awọn oogun ọhun abi awọn ti wọn ko fi orukọ wọn silẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Doctor Joy Adesina: Kìí ṣe gbogbo ìgbà náà ni mo fi ń kàwé ní fásitì, ẹ gbé ìgbé ayé tó dọ

  Dokita Joy Adesina ni akẹkọgboye ti yoo kọkọ gba iru awọn ami ẹyẹ yii ninu itan ile ẹkọ giga OAU to ti jade.

 3. Video content

  Video caption: Tradomedical Doctor Oluseyi Atanda: Báyìí ni mo ṣe ń fi ìṣègùn òyìnbó àti ti ìbílẹ̀ tọ́jú

  Oluseyi ba BBC Yoruba sọ nipa bo ṣe n ko imọ iṣegun mejeeji yii pọ. Bo ba ṣee ni ti oyinbo ti ko jẹ, a si ti ẹsẹ ile bọ ọ boya ifa yoo jẹ.

 4. Video content

  Video caption: Ilé wó lu Bisi, ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ kú, wọ́n gé ẹsẹ̀ rẹ̀ tó ń jẹrà, inú ìrora ló wà ṣùgbọ́n
 5. Ile epo

  Minisita keji fọrọ epo rọbi wa n rọ awọn alagbata epo lati mase sọ owo ọja wọn di ọwọn tabi ti ileepo wọn pa, ki ọwọn gogo epo le wa fun araalu.

  Kà Síwájú Síi
  next