Siga Mimu

  1. Video content

    Video caption: Njẹ ọ mọ̀ pé mímí afẹ́fẹ́ tí kò dára lè fa àìsàn?

    Ajọ eleto ilera lagbaye, WHO ni ẹni to n mi eemi ti ko dara sinu dabi ẹni to n fa siga mejila lojoojumọ.