Orilẹede Bangladesh

 1. Video content

  Video caption: Bangladesh Brothel: Ọ̀pọ̀ àwọn àṣẹ́wó tó wà níbẹ̀ ni wọ́n bí sílé aṣẹ́wó náà

  Ninu iwadi BBC,ọpọ awọn aṣẹwo to wa nile asẹwo to tobi julọ ni agbaye naa lo fẹ kuro nibẹ ti wọn ba ti ri owo lati gbe aye to dara.

 2. couple

  Khadijah, ọmọ ọdún mọ́kàndínlógún tó kó àwọn ọgọ́rùn ún ènìyàn lọ sílé ọkọ àfẹ́sọ́nà rẹ láti ṣí ojú àwọn obìnrin sí àṣà yii.

  Kà Síwájú Síi
  next