Ipinlẹ Katsina

 1. Awọn agbebọn

  Alukoro ile iṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Kaduna, Isa Gambo fidi rẹ mulẹ pe awọn janduku agbebọn to ṣọṣẹ ni abule Mado le lọdunrun un.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Amotekun

  Ninu ọrọ ti wọn ba BBC Yoruba sọ, wọn ni ṣùgbọ́n wọ́n gbọdọ̀ gba àṣẹ lọ́wọ́ ọlọ́pàá ati peo ṣeni laanu pe odidi gomina ipinlẹ lo n sọ fun araalu pe ki wọn lọ ra ibọn lati daabo bo ara wọn.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Ìgbìmọ̀ ẹlẹni 145 ni yóò ṣe ètò ìgbáyàwó ọmọ ààrẹ Buhari pẹlu ọmọ Emir Bichi

  Ìgbéyàwó yìí yóò wáyé ni ogúnjọ oṣù kẹjọ ọdún 2021, nígbà tí ètò ìwúye ọba yóò wáyé ni ọjọ́ kejì lélógúnni ààfin Emir.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Àwọn olórí ìjọ méjì ni wọn jí gbé ní ìjọ àgùdà ní Katsina- Rev Fr Chris

  Sùgbọ́n ó ṣeni láànú pé , òkú Fada Bello ni wọn pada rí nínú oko rúsúrúsú kan ní ẹyin sọ́ọ̀sì, sùgbọ́n wọ́n ji Fada Keke gbé lọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Dog

  Kọmiṣonna fun eto ẹkọ ipinlẹ ọhun, Badamasi Lawal Chiranci sọ fun BBC pe ijọba ipinlẹ naa ti pese 580 miliọnu ti wọn yoo fi kọ ogiri yii awọn ile ẹkọ naa ka.

  Kà Síwájú Síi
  next