Awọn Ounja oloro

 1. Video content

  Video caption: Akomolede ati Asa Yoruba: Bí wọ́n bá fi màrìwò ọ̀pẹ lé ara ọkọ̀, ṣé o mọ̀ ìtúmọ̀ rẹ̀?

  Ṣe o gbọ tuntun pe bi o bọ fi kun tabi yọ kuro lara ohun ti wọn fi pa aroko, o ti ba iṣẹ jẹ?

 2. Awọn ohun ija oloro

  Atẹjade ti Audu Ogbeh fisita, to pe ni 'Awọn ẹnu bode wa ati aifararọ eto aabo', tun ni lati orilẹede to mule ti Naijiria ni wọn ti n ko ohun ija oloro wa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: African Eye: Ìwádìí BBC lórí ikú tó pa ọmọ ogun 26 ní Libya láti ipasẹ̀ Díróònù àìmọ̀dí

  BBC Africa Eye ṣe àwárí rẹ̀ pé, ilẹ̀ United Arabi Emirate UAE ati Egypt lo n fi diroonu sere ọwọ lorilẹede Libya, eyi ti ko jẹ ki ogun sinmi nibẹ.

 4. Iran

  Ile iṣẹ ogun Iran ni awọn ṣéèṣì yin "missile" sinu afẹfẹ eyi to fori sọ ọkọ bàálù Ukrain to si fi ẹmi èrò ṣòfò.

  Kà Síwájú Síi
  next