Orilẹede Brazil

 1. Video content

  Video caption: Helgies Bandeira: Ọ̀pọ̀ oúnjẹ Yorùbá ni à ń jẹ ni Brazil

  Helgies Bandira tó jẹ́ aṣojú Brazil ní Nàìjíríà ní Ògún, Ọ̀ṣun, Ọbàtálá àti Yemọja wà lára àwọn Òrìṣà tiwa náà ní Brazil

 2. Ikọ ẹgbẹ agbabọọlu Naijiria ati Brazil

  Ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ ọlọ̀ọ́rẹ́sọọ̀rẹ́ tó wáyé láàrin ikọ̀ agbábọ́ọ́lù Naijiria àti Brazil parí sí ọ̀mì

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Brazil Yoruba: A n gbé àwọn ère Yorùbá káàkiri- Ọọni ti Ilé Ifẹ

  Ọba Adeyeye Ogunwusi ṣàlàyé nípa àwọn ọmọ Yorùbá tó tó mílíọ̀nù 80 si 100 tí wan ń gbé ni Brazil àti ohun ti Ilé Ifẹ fẹ́ ṣe báyìí.