Ìkọlù àwọn darandaran

 1. Ondo

  Ọga ọlọpaa to n ṣakoso agbegbe Ikare Akoko, ACP Razak Rauf ṣalaye pe lootọ ni wọn doola awọn meje ti ajinigbe ti kọkọ gbe lọ, awọn eeyan naa ko si ṣẹṣe rara.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Kayeefi: Ìdí gaan tí àwọn ìlú Ibarapa ṣe yarí pé àwọn ò fẹ́ Fulani nílùú mọ́ rèé

  Awọn ara Ibarapa ṣipaya ẹdun ọkan wọn ati bi wọn ko ṣe le gbagbe iṣẹlẹ naa laelae.

 3. Maalu

  Alukoro fun ileeṣẹ ọlọpaa nipinlẹ Ondo, Tee-Leo Ikoro rọ awọn oloye naa lati yọju sawọn ọlọpaa niluu Abuja.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Video content

  Video caption: Femi Falana, Endsars: Awolowo kò fáààyè gba kí èèyàn máa yàgò fún Màálù nígboro

  Femi Falana sọ̀rọ̀ lórí ọ̀rọ̀ àwọn darandaran, iwọde awọn ọdọ àti eto aabo Naijiria.