Ẹkun Iwọ oorun Afirika

 1. Aarẹ Buhari atawọn minisita

  Àèrẹ orílẹ̀eèdè Naijiria, Muhammadu Buhari ti sọ pé iṣẹ́ ibi àwọn alákatakítí ẹ̀sìn ni ìṣòro gbòógì tń ń kojú ìwọ̀ oòrùn Afrika.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Victor Osimhen atawọn akẹgbẹ rẹ

  Ẹgbẹ agbabọọlu Lesotho ti wọn n pe ni Crocodiles ta ọmi 1-1 pẹlu Sierra Leone l'Ọjọru ninu ifẹsẹwọnsẹ lati pegede fun idije 2021 AFCON.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Awọn ẹlẹwọn

  Ọọdunrun naira le diẹ lawọn elewọn n gba lọdun bayii lati 1979 nijọba ti ṣe agbeyẹwo owo oṣu awọn ẹlẹwọn kẹyin.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Aarẹ Putin ati Basir

  Se bí orilẹede Russia tun ṣe fẹ ṣàgbéǹde okoòwò rẹ̀ ní Áfíríkà yóò sọ́ di alágbára nílẹ̀ náà bí? Ẹka to n sewadi aridaju ohun gbogbo se agbeyẹwo boya Moscow ni yoo jẹ alagbara ni Áfíríkà.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Aworan ọmọ ti wọn ipa ba lopọ

  Ọmọ ọdun meje ni oniroyin Elizabeth Ohene wa nigba ti iṣẹlẹ naa ṣelẹ, ṣugbọn ko sọ fun ẹnikan nigba nigba naa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 6. Awọn eeyan lahamọ ni Kaduna

  Ileeṣẹ ọlọpaa fidi rẹ mulẹ pe awọn eeyan naa ti gbogbo wọn jẹ ọkunrin wa lati orilẹede Burkina Faso, Mali atawọn orilẹede ile Afirika miiran.

  Kà Síwájú Síi
  next
 7. Ẹnu ọna abawọle ibudo isegun fasiti Ibadan

  Ọjọgbọn Olubunmi Olapade Olaopa ni lọdun to kọja, ipo kẹjọ ni ibudo naa wa nilẹ Afirika lẹyin Fasiti Makerere to wa ni Uganda.

  Kà Síwájú Síi
  next