Ile-ẹjọ Odaran lagbaye

 1. Sunday Igboho

  O to wakati mẹfa ti igbẹjọ Sunday Igboho fi waye pẹlu isinmi ranpẹ laarin, sugbọn ileẹjọ pasẹ pe ki Igboho wa ni ahamọ titi di asiko igbẹjọ miiran lọsẹ to n bọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Ọlọpaa Naijiria

  Muhammed Adamu rọ awọn ọlọpaa lati raga bo ara wọn lọwọ ikọlu araalu.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Maryam

  Maryam Sanda ti fi iwé ranṣẹ si ile ẹjọ nipasẹ àwọn agbẹ́jọrò rẹ, Rickey Tarfa, Olusegun Jolaawo, Rigina Okotie-Eboh àti Beatrice Tarfa, pẹlu ariyanjiyan pe adajọ ṣe idájọ náà lọ́na aitọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Abdullahi

  Agbẹjọ́rò Tayo Fatogun jẹ́ kó di mímọ̀ pé, bí ọ̀gá àgbà àjọ ẹ̀ṣọ́ aṣọ́bodè ṣe wẹ̀ mọ́ nínú ẹ̀sùn jìbìtì wà lábẹ́ òfìn àti agbára adájọ́ àgbà.

  Kà Síwájú Síi
  next