Ileesẹ Ologun

 1. Ọta ibọn ologun

  Alagba kan ni adugbo ọhun to ba ikọ BBC Yoruba sọrọ wi pe ọrọ naa ti wa ní ile ẹjọ nitori ko si iyipada lati ọdọ awọn ọmọ ologun, lẹyin ti awọn lọ parọwa fun wọn.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Amugbalẹgbẹ Sunday Igboho meji ti DSS sẹsẹ tu silẹ

  Amofin Pelumi Olajengbesi ni gbogbo ilana to yẹ ní àwọn ti tẹle lati gba itusilẹ awọn eeyan mẹrin to ku si ahamọ amọ DSS kan pinnu láti ṣe ohun to wu ni.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Awọn ọmọ ologun

  Femi Falana ni abọ iwadii ileesẹ ologun ti Buhari se ti fihan pe awọn aadọrin sọja naa ko jẹbi ibeere wọn fun ipese ohun ijagun to poju owo lati doju kọ Boko Haram.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. NDA Attack: Ìkọlu sí NDA yìí ní yóò múṣẹ́ ya lórí fífi òpin si ìwà ọ̀daràn ní Nàìjírà- Ààrẹ Buhari

  Ààrẹ kẹ́dùn pẹ̀lú àwọn ẹbí tí wọ́n pàdánù ènìyàn wọn , ti o sì gbàdúra kí ọlọ́run tù wọ́n nínú.

  Kà Síwájú Síi
  next