Orilẹede Pakistan

 1. Aworan Malala nigba to wa si Naijiria

  Malala ati ololufẹ rẹ, Asser Malik ṣe nikkah wọn nibi ti wọn ti so awọn mejeji pọ ni ilana ẹsin Musulumi.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. By Riaz Sohail

  BBC Urdu, Karachi

  Awọn ẹbí iyawo tuntun fi iya nla jẹ Asif Rafiq Siddiqi.

  Wahala bẹ silẹ nibi igbeyawo kan ni Karachi lẹyin ti aṣiri tu pe ọkọ iyawo ti ni iyawo meji tẹlẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Mike Pompeo

  Àkọ̀wé ìjọba ilẹ̀ Amẹrika sọ pé wọ́n ti fi Naijiria sára àwọn orílẹ̀èdè tí wọ́n ń ṣọ́ lọ́wọ́ lẹ́sẹ̀ látàrí ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Ilu kano

  Ìròyìn kan ti sọ pé Kano ló ní ìdọ̀tí inú afẹ́fẹ́ jùlọ ní gbogbo ilẹ̀ Afirika, tí iwọ́n èérí afẹ́fẹ́ ìlú náà sì lé ní ìdá mẹ́tàlélàádọ́ta.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Pakistan

  Àjọ́ òsìsẹ́ pàjáwìrì ní ó seése kí iye àwọn ènìyàn tó kù ju bẹ́ẹ̀ lọ nítorí ènìyàn ogójì ló farapa nínú iná ọhún.

  Kà Síwájú Síi
  next