Tí a fiṣọwọ́ ní 20:03 27 Bélú 201920:03 27 Bélú 2019Chelsea àti Valencia pín gaàrí lọ́gbọọgba nílé ValenciaValencia lo kọkọ gbayo sawọn Chelsea lẹyin ti Carlos Soler jẹ goolu akọkọ nigba ti ifẹsẹwọnsẹ ọhun di ogoji iṣẹju.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 19:52 23 Bélú 201919:52 23 Bélú 2019Manchester City pàdí ọrẹ dà f'ogun ẹ̀yìn ja ChelseaFrank Lampard to jẹ akọnimọọgba Chelsea funra rẹ ti figba kan gba bọọlu fun Man City lẹyin to kuro ni Chelsea.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 21:40 30 Ọ̀wàrà 201921:40 30 Ọ̀wàrà 2019Ole mórí bọ́! Manchester United tún wẹ̀wù ìyà fún Chelsea lẹ́ẹ̀kan síiẸgbẹ agbabọọboolu Manchester United ya ọpọ lẹnu lẹyin ti wọn fiya jẹ Chelsea mọle ninu idije Carabao Cup.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 6:06 18 Owewe 20196:06 18 Owewe 2019Liverpool ṣubú dàánù ní NapoliGbogbo ireti awọn ololufẹ Liverpool ati onwoye ere bọọlu pe Liverpool yoo jawe olubori lo ja si pabo.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 13:32 17 Owewe 201913:32 17 Owewe 2019Tani yóò gba ife ẹ̀yẹ UEFA Champions League ti saa yi?Nínú ìdíje Champions League tí yóò bẹ̀rẹ̀ lónìí ni àwọn ẹgbẹ́ agbábọ́ọlù jàǹkọ̀ jàǹkọ̀ yóò ti gbéná wojú ara wọn.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 15:16 7 Owewe 201915:16 7 Owewe 2019Samuel Eto o fi búùtù bọ́ọ̀lù rẹ̀ kọ́, Ó ní òun kò gbá bọ́ọ̀lù mọ́Samuel Eto o ; Mo ti fi àdàgbá bóòlù kọ ó dìgbà kan ná.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 16:04 24 Ògún 201916:04 24 Ògún 2019Ọwọ́ ba Ole! Crystal Palace pàkúta sí gaàrí Manchester United ní Old TraffordCrystal Palace wàhálà sí Manchester United lágbada lẹ́yìn tí wọ́n ṣíná fún wọn pẹ̀lú àmì ayò méjì sí ẹyọ̀kanKà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 20:04 14 Ògún 201920:04 14 Ògún 2019Lampard wọ gàu! Chelsea tún ṣubú dàánù sọ́wọ́ LiverpoolLiverpool na Chelsea gba ife lyẹ ìdíje UEFA Super Cup nílùú Istanbul ní orílẹ́èdè Turkey.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 4:43 13 Ògún 20194:43 13 Ògún 2019Manchester United dáná sun Chelsea bi ẹràn àgbò iléyáAnthony Martial àti Daniel james náà ràn Red Devil lọ́wọ́ láti jáwe olúbori Chelsea ninu ìdíje tó dabi pé ó fẹ́ kó Chelsea lóyìí ojú.Kà Síwájú Síinext