Awọn foonu alagbeka ati awọn foonu ayara fefe

 1. NCC Alerts to Telcoms: Gbogbo ẹ̀yin ti ẹ n lo foonu, ṣe ẹ ti gbọ nipa "Flubot Malware

  Má tẹ ojú òpó ìlà kankan ti wọ́n ba fi àtẹjíṣẹ́ ránṣẹ́ sí ọ, bákan náà si ni kí o má gba áàpù tábi gba aapu ìdáàbòbo kankan sí orí fóònù rẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Aworan idanimo WhatsApp

  Koda, ẹgbẹ́ àwọn tó ń dá abo bo ẹtọ àwọn ọmọdé tí kò sì ọ̀rọ̀ pẹ̀lú ileese to jẹ ìyá Whatssap, ìyẹn Facebook lórí ọrọ yìí.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Uganda mobile phone user

  Ikede kan ti ajọ NCC gbe jade lo sọ pe bẹrẹ lati oṣu Keje ọdun 2021, awọn yoo maa beere nọmba IMEI gbogbo onibara ileeṣẹ ibaraẹnisọrọ.

  Kà Síwájú Síi
  next