Tí a fiṣọwọ́ ní 15:05 18 Sẹ́rẹ́ 202115:05 18 Sẹ́rẹ́ 2021Àwọn agbébọn ti jí àwọn arìnrìnàjò gbé ní ìpínlẹ̀ Osun!Ikọ Amọtẹkun ni ipinlẹ Osun to fi idi ọrọ naa mulẹ ni awọn ko le e sọ iye arinrinajo ti wọn jigbe.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 14:23 18 Sẹ́rẹ́ 202114:23 18 Sẹ́rẹ́ 2021Àwọn agbébọn ti yìnbọn pa igbákejì akọ̀wé FUTAYatọ sí Ọmọwe yìí, wọn tún yinbọn sí awakọ rẹ àti ọkunrin kan ti wọn ko darukọ.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 13:42 18 Sẹ́rẹ́ 202113:42 18 Sẹ́rẹ́ 2021Gbogbo ẹ̀yin Fulani darandaran tó wà ní ìgbó ìjọba ní Ondo, ọjọ méje lẹní láti pòórá - Gomina AkeredoluLaipẹ yii naa ni Sunday Igboho fun awọn Fulani darandaran ni gbedeke ọjọ meje lati kuro ni agbegbe Ibarapa, ni ipinlẹ OyoKà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 6:01 18 Sẹ́rẹ́ 20216:01 18 Sẹ́rẹ́ 2021N1.4bn ni ìjọba ìpínlẹ̀ Ekiti yòó ná lórí Amotekun lọ́dún 2021Kọmiṣọnna eto iṣuna ni ijọba ya owo naa sọtọ fun eṣọ Amotekun nitori bi eto abo ti mẹhẹ kaakiri orilẹede Naijiria bayii.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 4:30 18 Sẹ́rẹ́ 20214:30 18 Sẹ́rẹ́ 2021Sunday Igboho fún Fulani Oyo ní gbèǹdéke, Seriki fulani yarí, ọlọ́pàá dá síi...Wahala ijinigbe ati ipaniyan lagbegbe Ibarapa ni ipinlẹ Ọyọ n di lemọlemọ lẹnu ọjọ mẹta yii.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 13:59 16 Sẹ́rẹ́ 202113:59 16 Sẹ́rẹ́ 2021Ọwọ́ tẹ ènìyàn méjì tó ń ta ayédèrú aṣọ iṣẹ́ ikọ̀ Àmọ̀tẹ́kùnLaipẹ yii ni iwadii ikọ Amọtẹkun ni awọn ajoji ti kii ṣe ọmọ Naijiria n wọ ipinle Oyo ati Ogun.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 8:56 14 Sẹ́rẹ́ 20218:56 14 Sẹ́rẹ́ 2021Seyi Makinde ní ọwọ́jà Covid-19 kò rinlẹ̀ bí NCDC se kéde èèyàn 120 tó ní àrùn lọ́jọ́ kan l‘OyoAtẹjade ajọ NCDC fihan pe eeyan to le ni irinwo lo ko coronavirus laarin ọsẹ meji nipinlẹ Oyo.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 4:57 14 Sẹ́rẹ́ 20214:57 14 Sẹ́rẹ́ 2021Ọ̀dọ́ Bauchi ṣe àríyá ìbálòpọ lẹ́yìn tí àpèjẹ oníhòòhò forí ṣánpọn ní KanoAgbẹnusọ fun ileesẹ ọlọpaa ni Bauchi, Wakil Ahmed lo sisọ loju ọrọ yii lasiko to n safihan awọn afurasi naa fawọn akọroyin l‘Ọjọru.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 6:16 13 Sẹ́rẹ́ 20216:16 13 Sẹ́rẹ́ 2021Afurasí ẹlẹ́gbẹ́ òkùnkùn mẹ́rìnlá tó pa èèyàn mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n fojúhàn l‘OgunKọmisana ọlọpaa fikun pe ọwọ sinku ileesẹ oun ti ba eeyan mẹrindinlogun lapapọ, ti wọn si ba awọn ohun ija oloro lọwọ wọn.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 5:24 13 Sẹ́rẹ́ 20215:24 13 Sẹ́rẹ́ 2021Ẹ̀yin adarí Nàíjíríà, ẹ dẹ́kun àwáwí asán lórí ètò ààbò tó mẹ́hẹ - Ààrẹ àṣòfin àgbàSẹnetọAhmad Lawan ko ṣai gboṣuba fawọn aṣofin fun iṣọkan to wa laarin wọn bo tilẹ jẹ pe ọtọọtọ lẹgbẹ oṣelu wọn.Kà Síwájú Síinext