Orilẹede Ethiopia

 1. Video content

  Video caption: Africa Eye Migrants: Àwọn tó ń fẹsẹ̀ rìn sálọ orílẹ̀èdè míì ṣe fídíò ráńṣẹ́ sílé

  Iṣẹlẹ yii ko jẹ ko ya eeyan lẹnu pe wọn n ku lọna tabi ki ọpọlọpọ wọn pada di atọrọjẹ loju popo.

 2. Gebru

  Atimọle akọroyin BBC yii lo n waye lẹyin ti awọn ologun naa ti kọkọ ti awọn eeyan meji to n ṣiṣẹ fun ileeṣẹ iroyin Agence France-Presse, AFP, ati Financial Times mọle.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Agbami naa

  Àwọn àwòrán tí wọn yà níbi adágún odò ọ̀hún fihàn pé àfikún ti ń bá òdiwọ̀n omi tó wà ní ibùdó ìṣe omi lọ́jọ̀ sí tó jẹ́ ti orílẹ̀èdè Ethiopia.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Rogbodiyan lorilẹ-ede Ethiopia

  Adarí ìgbìmọ̀ ìjọba Ethiopia, Abiy Ahmed sọ pé èèyan méjìdínlọ́gọ́rin ti dèrò ọ̀run látàri rògbòdìyàn kan tó bẹ́ sílẹ̀ lórílẹ̀-èdè ọ̀hún.

  Kà Síwájú Síi
  next