Ètò Ìdájọ́

 1. Video content

  Video caption: Makinde vs Adelabu: Makinde ní ìjọba Ọyọ yàtọ̀ sí ti Ọṣun àbí Ekiti tí APC lé dànù

  Gomina Seyi Makinde tun ni ibi gbogbo yika ipinlẹ Ọyọ ni wọn ti kọ ẹgbẹ APC, ki lo tun wa ku ti wọn fẹ se.

 2. Oju ọna to ye kooro

  Ile asofin naa ni ihàlẹ kò ran ọrọ tí ileesẹ ENL fẹ fà lẹsẹ yii rárá ju kí wọn múra láti mú ayé dẹrùn fún ará ìlú

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Makinde

  Gómìnà Seyi Makinde ti gbé iṣẹ́ lé ilé iṣẹ́ tó ń rí sí ọ̀rọ̀ obìnrin nípinlẹ̀ Oyo lọ́wọ́ lati setọju àwọn tí wọ́n tú sílẹ̀.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Atiku Abubakar ati Muhammadu Buhari

  Agbẹnusọ APC wá rọ wọn pé kí wọ́n ni sùúrù fún bí ọdún mẹta àti oṣù díẹ̀ láti tun gbe igbá ìdìbò míràn lọdun 2023.

  Kà Síwájú Síi
  next