Èkó

 1. Bobrisky

  Ohun to mu ọrọ yii wa ni bi Bobrisky ṣe tabuku Tonto Dikeh loju opo Instagram rẹ pe o wọ gbese ẹgbẹlẹgbẹ miliọnu naira.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Kazeem Abonde

  Ninu atẹjade ti alukoro ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko, Adekunle Ajisebutu fi ṣọwọ si awọn akọroyin, o ni ẹmi ọga ọlọpaa ọhun sọnu lasiko ti wọn lọ fofin de awọn ọlọkada lagbegbe ọhun.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Aworan awọn oluwọde EndSARS kan

  Ṣaaju eyi ni aileeṣẹ ọmọ ogun Naijiria ti kọkọ sẹ kanlẹ pe iroyin ofege ni iroyin to ni awọn lawọn yinbọn lu awọn oluwọde ni Lekki Tollgate.

  Kà Síwájú Síi
  next