Irin-ajo ofurufu

 1. Air Nigeria

  Minisita fun eto irinna ọkọ ofurufu naa ni o kere tan ileeṣẹ ọkọ ofurufu Air Nigeria naa yoo pese iṣẹ to to ẹgbẹrun lọna aadọrin fun awọn ọmọ Naijiria.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Endsars

  Ogunjọ, Osu Kẹwaa, ọdun 2021 ni awọn ọdọ ṣe ifẹhọnuhan ni agbegbe Lekki tako ifiyajẹni ati iṣekupani awọn ọmọ Naijiria gba ọwọ awọn ọlọpaa ni Naijiria.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Obinrin to n wa tirela

  Awọn to n fi baalu ko ẹru ni ohun to daa ni igbesẹ yi lọna ati tan iṣoro to de ba mimu ọja de ọdọ awọn to fẹ ra a.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Awakọ baalu to ja laarin awọn ọga ologun

  Oludari ẹka alarina ati eto iroyin fun ileesẹ ologun ofurufu, Edward Gabkwetto ni lọjọ Aiku, ọjọ Kejidinlogun osu Keje ọdun 2021 ni deede aago kan ku isẹju mẹẹdogun, ni isẹlẹ naa waye.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Video content

  Video caption: Flying car: Ọkọ̀ tí ń fò, ọ̀nà àbáyọ kan rèé sí ìṣòro 'go slow' lágbègbè rẹ

  Ni ilu Slovakia ni wọn ti kọkọ dan an wo.

 6. Video content

  Video caption: Covid-19 Pandemic funeral: A dáná sun odidi òkú èèyàn gẹgẹ bí àwọn mọlẹbí ṣe sanwó ẹ̀

  Àwọn ǹkan táa rí rí tẹlẹ tó máa ń ṣẹlẹ níbi ìsìnkú ni Bolanle Okusanya, Elétò abániṣayẹyẹ ìsìnkú sọ síta yìí.