Orilẹede Ivory Coast

 1. Amadou Gon Coulibaly

  Coulibaly, tii se ẹni ọdun mọkanlelọgọta ni ẹgbẹ to n se ijọba lọwọ ni orilẹ naa ti fa kalẹ bii oludije ninu ibo aarẹ to n bọ losu kẹwa ọdun yii.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. coronavirus

  Ènìyàn irínwólẹ́gbẹ̀rún ló tí ní àrùn Coronavirus káàkiri orílẹ̀èdè métalélọ́gọ́rín nínú orilẹède mẹrinlelaadọta tó wà ní ilẹ̀ Afrika.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Akeem Oseni

  Major Ogbemudia Osawe àti Nuhu Dogary ni wọ́n jọ dá ẹwọn ọdun méwàá fun pẹlu Oseni, sùgbọ́n Oseni fẹsẹ̀ fẹ ni tirẹ̀.

  Kà Síwájú Síi
  next