Ominira lati sọrọ

 1. Awọn iwe iroyin tako atunṣe ofin to de iṣẹ iroyin

  Ẹgbẹ awọn to ni iwe iroyin, NPAN ni ifẹhonuhan awọn ileeṣẹ iwe iroyin yoo tẹsiwaju lọjọ kẹtala oṣu keje.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Sunday Igboho's latest on Oduduwa Republic: Ìràn Yorùbá ò ní ìṣọ̀kan rárá ló ń fa gbogbo è
 3. Banji Akintoye ati Sunday Igboho

  O ni ṣaaju ki awọn oyinbo to de ni ibaṣepọ ti wa laarin awọn ẹya to parapọ di Naijiria.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Gebru

  Atimọle akọroyin BBC yii lo n waye lẹyin ti awọn ologun naa ti kọkọ ti awọn eeyan meji to n ṣiṣẹ fun ileeṣẹ iroyin Agence France-Presse, AFP, ati Financial Times mọle.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Video content

  Video caption: Francis Olusola Alao: Wọ́n ti ti ọ̀rọ̀ òṣèlú bọ ọ̀rs Sunday Igboho, ṣùgbọ́n..- Oba Olugbọn

  Ijọba ti kuna lojuṣe wọn lo jẹ ki awọn eeyan bii Sunday Ighoho dide lasiko yii- Oba Francis to jẹ Olugbon ti Orile Igbon