Awọn opo Ikansira ẹni lori itakun agbaye

 1. Video content

  Video caption: Kiki Osinbajo: T;o bá yá owó lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni, máa gbìyànjú láti da padà

  Kiki Osinbajo, tii se ọmọ igbakeji aarẹ, Yemi Osinbajo ba BBC Yoruba sọrọ nipa bo se bẹrẹ okoowo lai naani pe amofin ni oun.

 2. Mark Zuckerberg

  Zuckerberg sọ pe orukọ tuntun naa tumọ si pe ẹnikẹni to ba fẹ maa lo eyikeyi ninu awọn ohun ti ileeṣẹ naa n ṣe yoo ni lati kọkọ lo oju opo Facebook.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Ọ̀gá Bello: Àìgbọ́n ló ń da àwọn òsèré tíátà tó ń jà lórí ayélujára láàmú

  Ìlú-mọ̀ọ́ká òsèré tíátà, Adebayọ Salami ti ní àjọsepọ̀ gidi ń bẹ láárin ẹgbẹ́ òsèré tíátà ANTP àti Tapan.

 4. Aworan Instagram

  Awọn alaṣẹ ileeṣẹ Instagram n tọka si iṣẹlẹ idẹyẹsi to waye lẹyin ifẹsẹwọnsẹ aṣekagba idije Euro 2020 laarin ik agbabọọlu England ati Italy gẹgẹ bii ara ohun to sun wọn si igbesẹ tuntun yii.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Awon adigunjale

  Ofin NBC ni "oniroyin ko gbudọ gbe ohun to lee tu ilu ka jade lori afẹfẹ tabi to lee dẹru ba awọn araalu tabi fa ipinya".

  Kà Síwájú Síi
  next