Eto Iselu

 1. Awọn akẹṣẹ

  lo sọ lalẹ Ọjọru pe igbesẹ lati da idije naa duro waye nibi ipade ti igbimọ LOC ṣe eleyii ti igbakeji gomina ipinlẹ Edo, Philip Shaibu wa nibẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Ọgba ẹwọn Owerri

  Ikọlu mii tun waye si olu ileeṣẹ ọlọpaa miran ni ipinlẹ Imo lẹyin ọjọ kan ti ikọlu akọkọ waye

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Pasitor Bakare ati Biṣọọbu Kukah

  Pasitọ Tunde Bakare ni oun sọrọ soke tori iru Naijiria yii kọ ni oun ati ààrẹ Muhammadu Buhari pinu lati ni lasiko ti awọn jọ n dije dupo aarẹ lọdun 2011.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Igboho ati ami idam YWG

  YWG gba Yorùbá ní ìmọ̀ràn pé, ọ̀nà àbáyọ tó wà ni ki a pada sí ẹsẹ ààrọ́ níbí tí ẹkùn kọ̀ọ̀kan yóò tí má dari ọ̀rọ̀ ajé wọ́n.

  Kà Síwájú Síi
  next