Ẹka epo ati afẹfẹ gaasi

 1. Agolo afẹfẹ idana gaasi

  Ni bi a ṣe n sọrọ yii, owo agolo silinda oniwọn 12.5kg ti wọn n ra ni ẹgbẹrun mẹrin naira (N4000) loṣu kini ọdun 2021 gbera lọ si ẹgbẹrun meje ati ẹẹdẹgbẹrin naira (N7,800) loṣu kẹsan ọdun 2021 kan naa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Awọn isẹlẹ to n da ilu ru

  BBC Yoruba se akojọpọ awọn isẹlẹ akanilaya ti ko ba tun sọ orilẹede yii sinu ogun abẹle keji nibayii ta n sami ọdun Kọkanlelọgọta ti Naijiria gba ominira.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Ayederu owo naira ẹgbẹrun kan alapapọ

  Agbẹjọro ajọ DSS sọ nile ẹjọ pe laarin oṣu Kinni si oṣu Keje, ọdun 2021, ni awọn eniyan naa, ati awọn akẹẹgbẹ wọn to ti salọ, gbimọpọ lati lu awọn araalu ni jibiti.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Ile epo

  Minisita keji fọrọ epo rọbi wa n rọ awọn alagbata epo lati mase sọ owo ọja wọn di ọwọn tabi ti ileepo wọn pa, ki ọwọn gogo epo le wa fun araalu.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Video content

  Video caption: Ibadan Gas tanker accident: Ọdọọdún la máa ń gbé igbá àgbo lọ́jà Bode àmọ́ àwọn kan kọ̀ lọ

  Sàráà fún ọjọ́ méje ló yẹ ká ṣe àmọ́ àwọn kan kọ̀ ló fa ìjàmbá Táńkà gáàsì tó pa èèyàn - Iyaloja Bode Ibadan

 6. Aworan lati ibi ijmaba ọkọ ni Bode, Ibadan

  Gẹgẹ bi awọn to ṣoju wọn ṣe sọ ọ, ọkọ naa bẹrẹ si ni ṣina lati Idi Arere to si yi wọ inu ọja Bode.

  Kà Síwájú Síi
  next
 7. Epo Bẹntirol

  Agbẹnusọ fun ẹgbẹ IPMAN, Yakubu Suleiman ṣalaye pe, ẹgbẹ naa ti sọ fawọn ọmọ ẹgbẹ lati da iṣẹ silẹ nitori bawọn ọlọpaa ti n dunkoko mọ wọn.

  Kà Síwájú Síi
  next
 8. Muhammadu Buhari atawọn Niger Delta Avengers

  Ninu atẹjade kan ti ẹgbẹ Niger Delta Avengers ti fi sita, ni wọn ti ṣalaye pe awọn ṣetan lati ri pe ọrọ aje Naijiria dẹnu kọlẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next