Ipinlẹ Ogun

 1. Video content

  Video caption: Kayeefi: Ìdí gaan tí àwọn ìlú Ibarapa ṣe yarí pé àwọn ò fẹ́ Fulani nílùú mọ́ rèé

  Awọn ara Ibarapa ṣipaya ẹdun ọkan wọn ati bi wọn ko ṣe le gbagbe iṣẹlẹ naa laelae.

 2. G daniel

  Alukoro ẹgbẹ oṣelu PDP ti ṣalaye awuyewuye to n waye ẹyin ti gomina ipinlẹ Ogun tẹlẹ, Gbenda Daniel fi ẹgbẹ nbaa silẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Dapo Abiodun - MFR

  Iroyin ni awọn afurasi naa ṣekupa eeyan mẹta, ti wọn si tun jo ẹnikan mọle ni ijọba ibilẹ Ariwa Yewa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Sunday Igboho l'Ogun

  Odusile: Wọn sorí ifọrọwanilẹnuwo wa kodo ni lati fi sọ pe Dapo Abiodun lo ranṣẹ pe Igboho fun iranlọwọ lori ọrọ Fulani ajinigbe.

  Kà Síwájú Síi
  next