Ipinlẹ Sokoto

 1. Àwọn olórí ìjọ méjì ni wọn jí gbé ní ìjọ àgùdà ní Katsina- Rev Fr Chris

  Sùgbọ́n ó ṣeni láànú pé , òkú Fada Bello ni wọn pada rí nínú oko rúsúrúsú kan ní ẹyin sọ́ọ̀sì, sùgbọ́n wọ́n ji Fada Keke gbé lọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Ijapa atawọn dokita to n sisẹ abẹ fun

  Dokita Abubakar sọ fun BBC pe, ọmọ ẹni to ni ijapa ọhun, n fẹyin rin pẹlu ọkọ, lo fi ṣeeṣi gun ijapa naa lori, eyi to mu ki igba ẹyin rẹ fọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Ọọni Adeyeye Ogunwusi ati Sultan ti Sokoto

  Sultan tun gba awọn ọba alaye nimọran lati maa sọ otitọ lai bẹru pe gomina abi awọn alaga ijọba ibilẹ yoo dunkoko mọ wọn.

  Kà Síwájú Síi
  next