Olusegun Obasanjo

 1. Video content

  Video caption: Olagunsoye Oyinlola: Kí Olorun dáríjì wá lórí ọ̀rọ̀ yíi, a ti kùnà ìlérí wa fún ìran Yorùb

  Gomina ipinlẹ Osun tẹlẹ, Olagunsoye Oyinl;ola ṣalaye ipa to kọ ki Buhari to le wọle nilẹ Yoruba pẹ̀lú ẹdun ọkan lori ohun to n ṣele bayii.

 2. Nàìjíríà yóò túbọ̀ máa wojú Obasanjo fún ẹkọ́ ọgbọ́n àti ìmọ̀- Ààrẹ Buhari

  Obasanjo ni iroyin irọ ti wọn po pọ yii jade si oun gẹgẹ bi iyalẹnu tori pe fun igba diẹ, akitiyan awọn kan lati ṣaa fa oun wọ inu agbo oṣelu pọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. OlusegunObasanjo

  Olusegun Obasanjo sọrọ naa nibi ipade apero kan, to si ni eekan ilu kan lo de ba oun lalejo, to si ni ki oun sọ ootọ to wa nidi ahesọ iku Buhari.

  Kà Síwájú Síi
  next