Ọ̀wọ́ngógó epo bẹtiróólù

 1. Ami idanimọ NNPC

  PANDEF ní eyi fihan pe ijọba Buhari ko naani ohun tawọn eeyan agbegbe Niger Delta n la kọja, awọn eeyan yii si lo n foju wina ayika wọn to ti ba

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Buhari

  VOR ni bi aarẹ Buhari ṣe de ipo ni ọdun 2015 ko ṣẹyin ibaṣepọ laarin awọn ọmọ Yoruba, to gbaruku ti, pẹlu ileri pe oun yoo ṣe atunto orilẹede yii.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Ẹyin Ọmọ Naijiria, ẹ ma reti lati ra epo bẹntirol ni 200 naira o kere ju - IPMAN

  Arakunrin Osatuyi ni o da oun loju wi pe gbogbo nkan ni yoo gbe owo lori nitori epo bẹntirol lo ma n sọ bi ọja yoo ṣe ri lọrilẹede Naijiria.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Dino Melaye

  Dino Melaye wa gba ijọba nimọran lati jẹ ki atunto Naijiria tawọn araalu n beere fun waye, bibẹẹ kọ, funra ara atunto ni yoo se ara rẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next