Eto Irinna Oju-irin

 1. Shehu Sani

  Shehu Sani to fi iroyin naa lede ni ado oloro to ku lẹyin ti awọn agbesunmọmi ṣekọlu si ọkọ oju irin ni Ọjọọru ni ọkọ ou irin wọn gunle lori.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Ibadan train station: Ìrìrí àwọn aráàlúu Ibadan nínú ọkọ̀ Reluwé tuntun rèé

  Ti ẹ ba de awọn orilẹ-ede nla nla kaakiri agbaye, e oo ri awọn gbagede karatakata to sun mọ ibudokọ oju irin, iru rẹ ni ijọba Seyi Makinde fẹ ṣe siluu Ibadan.

 3. Seyi Makinde

  Kọmiṣọna fun iṣẹ ode ati eto irinna ni ipinlẹ naa, Ọjọgbọn Dahud Kehinde Shangodoyin lo sọ bẹẹ ninu ifọrọwerọ kan pẹlu BBC Yoruba.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Buhari, Rotimi Amaechi ati awọn eeyan mii lasiko ifilọlẹ naa

  Lara awọn eeyan jankan wa nibi ayẹyẹ ifilọlẹ reluwe ni Femi Gbajabiamila, Kayode Fayemi, Babajide Sanwo-Olu, Seyi Makinde ati Dapo Abiodun.

  Kà Síwájú Síi
  next