Awọn Iwe

 1. Video content

  Video caption: Wikipedia: Ẹ̀nìkan sọ fún mi pé iṣẹ́ ìdọ̀tí ni màá ṣe ni mo ṣe ń ta ìwé

  BBC Yoruba se alabapade ọkunrin kan, Adekola Ademuyiwa, ẹni to sọ awọn iriri rẹ nidi iwe tita lọ̀na awada ati ẹfẹ ati awọn iwọsi to wa nidi okoowo naa.

 2. Dilibe Onyeama, adulawọ akọkọ to pari iwe rẹ nile ẹkọ Eton,

  Dilibe Onyeama kọ iwe kan nipa iwa ẹlẹyamẹya ti oju rẹ ri nileewe naa ati bi ti ile ẹkọ naa ko se gba a laaye lati pada wa sibẹ mọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. JF Odunjo

  Lọdun 1951, J.F Odunjo dibo, to si wọle sile asofin lẹkun iwọ oorun Naijiria, kí wọn to tun yan an gẹgẹ bii Minisita fọrọ ilẹ ati osisẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. D.O Fagunwa

  Diipọ Fagunwa sọrọ iwuri lati seranti baba rẹ, D.O Fagunwa, to jade laye lọjọ Keje Osu Kejila ọdun 1963, eyi to pe ọdun mẹrindinlọgọta bayii.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Oladejo Okediji àti ìgbé ayé ìtàn kíkọ rẹ̀

  Àrá, ọ̀rẹ́, àwọn òǹkọ̀wé àti Mọ̀lẹ́bí olóògbé Oladejọ Okediji ń ṣe ìdáro bàbá tó yẹ kó ṣe ọjọ́ ìbí Àádọ́rùn ún ọdún láyé.

  Kà Síwájú Síi
  next