Tí a fiṣọwọ́ ní 7:41 27 Bélú 20207:41 27 Bélú 2020Báyìí ni àgbàọ̀jẹ̀ agbábọ́ọ̀lù Diego Maradona ṣe wọ káà ilẹ̀ lọ lólú ìlú ArgentinaIlumọọka agbabọọlu ọmọ ilẹ Argentina Diego Maradona dagbere faye lẹni ọgọta ọdun l'Ọjọru.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 9:34 26 Bélú 20209:34 26 Bélú 2020Ohun mẹ́wàá pàtàkì nípa Maradona àti ìbáṣepọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú ẹlẹ́sẹ̀ ayò Diego Costa rèéDiego Maradona wa lati idile ti wọn ko ṣaaba rọwọ fi họri, o si goke agba di agbaọjẹ agbabọọlu kaakiri agbaaye.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 18:22 25 Bélú 202018:22 25 Bélú 2020Àwòrán rèé nípa bí 'Hand of God' ṣé dí inagijẹ Diego MaradonaOrisi aworan lo safihan igbe aye gbajugbaja agbabọọlu to ṣe akọnimọọgba Messi.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 16:17 18 Bélú 202016:17 18 Bélú 2020Ṣé òwe ilé ńtó lọ kọ́ nìyí fún Gernot Rohr, akọ́nimọ̀ọ́gbá Super Eagles?Ifẹsẹwọnsẹ Naijiria ayi Serea Leone lo fa ibinu awọn ololufẹ ere bọọlu yọ.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 10:11 4 Bélú 202010:11 4 Bélú 2020Diego Maradona ṣiṣẹ́ abẹ lórí ẹ̀jẹ̀ tó dì sí i lọ́pọlọ lẹ́yìn ọjọ́ ìbí ọgọ́ta ọdúnDokita gbajugbaja agbabọọlu naa, Leopoldo Luque lo ṣi aṣọ loju eegun ọrọ yii fawọn akọroyin.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 10:39 13 Owewe 202010:39 13 Owewe 2020Willian pa itú méje ní ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ rẹ̀ àkọ́kọ́ fún ArsenalSaa liigi tuntun Premiership bẹ̀rẹ̀ ni ilẹ Gẹẹsi lọjọ Abamẹta, Fulham ati Arsenal lo si ṣide rẹ.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 6:27 11 Owewe 20206:27 11 Owewe 2020Lẹ́yìn ọ̀pọ̀ ọdún, ìjọba Kwara fẹ́ sọ orúkọ Rashidi Yẹkini di mánigbàgbéGomina ipinlẹ Kwara lọ sọ bẹẹ lasiko to ṣe abẹwo si minisita fun ọrọ ere idaraya ni Naijiria, Sunday Dare ni Abuja.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 10:37 21 Èbibi 202010:37 21 Èbibi 2020Ronaldo Brazil làgbà gbogbo agbábọ́ọ̀lù, kì í ṣẹgbẹ́ ẹ Messi àti Ronaldo- Roberto CarlosRonaldo Delima gba gbajugbaja ami ẹyẹ Ballon d'Or lẹẹmeji, o si tun gba ife ẹyẹ agbaye lọdun 1994 ati 2002.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 11:51 13 Èbibi 202011:51 13 Èbibi 2020Wo àwọn orílẹ̀-èdè márùn ún tó fún àwọn obìnrin làńfàní tuntun sí ẹ̀tọ́ wọnWo àwọn orílẹ̀-èdè míì tó fún àwọn obìnrin làńfàní tuntun bíi Saudi Arabia, Iran, àti Pakistan.Kà Síwájú Síinext
Tí a fiṣọwọ́ ní 11:39 8 Èbibi 202011:39 8 Èbibi 2020NFF fi #30,000 kún #10,000 owó ìrànwọ́ oṣooṣù fún ìyá Rashidi Yekini àti Samuel OkwarajiRashidi Yekini ṣi ni aṣiwaju atamatase agbabọọlu fun ilẹ Naijiria ninu itan.Kà Síwájú Síinext