Orilẹede Ukraine

  1. Video content

    Video caption: Larisa: Má jẹ́ kí ọjọ́ orí rẹ dí ẹ lọ́wọ́ láti bẹ̀rẹ̀ ohunkóhun to wù ọ

    Larisa Mikhaltsova fi iṣẹ́ olùkọ́ èwe sílẹ̀ ló di ìlúmọ̀ọ́ká arìnrìn oge lọ́mọ ọdún mẹrindinlaadọrin.