Ipolowo Ọja

 1. Video content

  Video caption: Trade by Barter, Rivers: Mọ̀ síi nípa ọjà ní Esuk Mba, níbití o ti lè fi iṣu gba edé, epo

  BBC ṣabẹwo si ọja Satide, Satide yii lati ṣafihan ọja ti wọn ki i na owo nibẹ bikoṣe pasipaarọ ohun ini

 2. Video content

  Video caption: Akomolede àti Asa: Ìyàtọ̀ tó wà láàrin ìlànà ìpolówó ọjà láyé àtijọ́ àti òde òní

  Lori eto Akomolede ati Asa lọsẹ yii, olukọ wa, Olayinka aya Olorunyolemi, tile ẹkọ girama St Louis nilu Akure kọ wa nipa ipolowo ọja nilẹ Yoruba.

 3. Ilesha Baruba Clash: Ìjọba ìpińlẹ̀ Kwara bá ẹbi àwọn tó sòfò ẹ̀mí kẹ́dùn ni Baruteen

  Wọ́n ni ìjà náà bẹ́ sílẹ̀ nítori owó tí àwọn ọlọ́kọ̀ máa n san ti wọ́n bá fẹ́ gbe ìrẹsì wọ inú ọja Sinawa tó wà ni ìlú Ilésha Baruba.

  Kà Síwájú Síi
  next