Iranlọwọ fawọn Alaini

 1. Muhammadu Buhari

  Amẹrika wa fi iwadii ati bi wọn ti fi ọwọ ofin mu alaga ajọ EFCC to n gbogun ti iwa ibajẹ, Ibrahim Magu lori ẹsun iwa ajẹbanu, ṣe àpẹẹrẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Ijọba n pin owo iranwo nipinlẹ Ogun

  Hajiya Faruq ti akọwe agba ileeṣẹ ijọba naa, Bashir Alkali ṣoju nibi ayẹyẹ ọhun ṣalaye pe eto naa wa fun fifa awọn ti ko rọwọ họri soke.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: John Amanam: Ìfẹ́ tí mo ní sí àbúrò mi ló sọ mi dí ẹni tó ń ṣe 'Prosthetic' báyìí

  Ubokobong Sunday ṣalaye ohun ti oju rẹ ri to ki ẹgbọn rẹ tó báa ṣe ọwọ atọwọda to n lo bayii.

 4. Iyawo tuntun

  Sẹ́nẹ́tọ̀ Kabiru Marafa sọ pé, òun ṣe ìrànwọ́ yìí ni nítorí pé òun wòye bí àwọn ọmọ tí àwọn agbébọn sọ di ọmọ òrukan ṣe pọ̀ tó ní Ìpínlẹ̀ náà.

  Kà Síwájú Síi
  next