Agbara nini Ounja oloro

 1. Awọn ẹrọ amunawa

  Amọ aba naa ni awọn eeyan to n se akansẹ isẹ pataki yii gbọdọ gba asẹ lọdọ minisita fọrọ ohun amusagbara, ki wọn to lo ẹrọ amunawa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Osisẹ mọnamna kan n lọ waya ina lori opo

  Awọn ileeṣẹ apinna ni Naijiria, DISCOs ni ẹru wiwo ni ijọba n di le awọn lori nipasẹ airikanṣekan wọn lẹka ipese ina ọba.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Waya to n pin ina ọba

  Ọpọ eeyan lori ayelujara ni wọn di ẹbi ina ọba to n ṣe ṣegesẹge ru minisita ile iṣẹ mọnamọna tẹlẹri, Babatunde Fashola.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Iran

  Ile iṣẹ ogun Iran ni awọn ṣéèṣì yin "missile" sinu afẹfẹ eyi to fori sọ ọkọ bàálù Ukrain to si fi ẹmi èrò ṣòfò.

  Kà Síwájú Síi
  next